Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Òbí

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Òbí

Ó dájú pé wàá ti kíyè sí pé inú Bíbélì la ti yọ àwọn ìmọ̀ràn tó wà nínú ìwé yìí. Ìdí sì ni pé Bíbélì ló lè fúnni ní ìmọ̀ràn tó dára jù lọ tó lè ran gbogbo ẹni tó wà nínú ìdílé lọ́wọ́. Àwọn ìlànà inú rẹ̀ lè mú kéèyàn ronú lọ́nà tó dára, kéèyàn sì ṣe ìpinnu tó máa yọrí sí rere.​—Òwe 1:1-4.

BÍBÉLÌ TÚN LÈ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ PÀTÀKÌ BÍI:

A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí fúnra rẹ nínú Bíbélì. Wo fídíò náà Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Lo ìlujá yìí tàbí kó lọ sí ìkànnì jw.org/yo