Yorùbá
Nǹkan Ń Gbówó Lórí! Ọgbọ́n Wo Lo Lè Dá Sí I?—Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/102025008/afrn/art/102025008_afrn_sqr_xl.jpg
g25 No. 1 ojú ìwé 16

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I

Lọ sí jw.org, tẹ àkòrí náà “Iṣẹ́ àti Owó” sínú àpótí tá a pè ní “Wá a”. Lábẹ́ àkòrí yìí, wàá rí àwọn àpilẹ̀kọ tá a dìídì ṣe nípa ohun téèyàn lè ṣe tí kò fi ní máa kọ́kàn sókè ju bó ṣe yẹ lọ tí nǹkan bá nira, àwọn àpilẹ̀kọ yìí sì ti ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́. Díẹ̀ lára àwọn àkòrí tí wàá rí níbẹ̀ rèé:

Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Owó

Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná

Ṣe Bó O Ti Mọ—Bí O Ṣe Lè Ṣe É

Ayé Dojú Rú—Ṣe Ohun Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Àtijẹ Àtimu Nira Fún Ẹ