Yorùbá
Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí: Àwọn Èèyàn Ti Ba Ayé Yìí Jẹ́ Gan-An!​—Ṣé Ọ̀nà Àbáyọ Wà?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/102023010/univ/art/102023010_univ_sqr_xl.jpg
g23 No. 1 ojú ìwé 16

Xuanyu Han/Moment via Getty Images

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ojoojúmọ́ làwọn èèyàn túbọ̀ ń sọ ayé yìí di ibi tó léwu.

Ṣé wọn ò ní ba ayé yìí jẹ́ kọjá àtúnṣe, débi tí ohun alààyè kankan ò fi ní lè gbébẹ̀ mọ́? Ka àwọn àpilẹ̀kọ yìí kó o lè mọ oríṣiríṣi ohun táwọn èèyàn ti ṣe láti ba ayé yìí jẹ́, kó o sì rí àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé ọ̀nà àbáyọ wà.

Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sáwọn nǹkan yìí lọ́jọ́ iwájú?

  • Omi tó mọ́

  • Òkun

  • Igbó kìjikìji

  • Afẹ́fẹ́