Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”

“Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”

Inú Òwe 14:30 ni ọ̀rọ̀ yìí wà, wọ́n sì ti kọ ọ́ ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ọdún sẹ́yìn! Ó jẹ́ ara ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wúlò nígbà gbogbo tó wà nínú Bíbélì. Tó o bá fẹ́ mọ púpọ̀ sí i, lọ wo ìkànnì jw.org. Wàá rí àwọn fídíò, eré bèbí, ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àtàwọn àpilẹ̀kọ tó dá lé oríṣiríṣi ẹ̀kọ́ tó lè ranni lọ́wọ́, títí kan béèyàn ṣe lè ní ìbàlẹ̀ ọkàn. Àwọn àpẹẹrẹ kan ló wà nísàlẹ̀ yìí:

ÀWỌN ÒBÍ