Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ILÉ ÌṢỌ́ No. 6 2017 | Ẹ̀bùn Wo Ló Ju Gbogbo Ẹ̀bùn Lọ?

Kí Lèrò Rẹ?

Ta ni ẹni tó ga jù lọ láyé àti lọ́run tó ń fúnni ní ẹ̀bùn?

“Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé jẹ́ láti òkè, nítorí a máa sọ̀ kalẹ̀ wá láti ọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá.”​Jákọ́bù 1:17.

Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí jẹ́ ká mọ ẹ̀bùn pàtàkì kan tí Ọlọ́run fún wa àti bó ṣe ju gbogbo ẹ̀bùn lọ.

 

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

“Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Tí Mo Rí Gbà Nìyí”

Ṣé wàá fẹ́ gba ẹ̀bùn tàbí kó o fúnni lẹ̀bùn tẹ́ni tó o fún á mọyì tọkàntọkàn?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bá A Ṣe Lè Rí Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Fúnni

Ó máa ń gba ìsapá gan-an ká tó lè rí ẹ̀bùn fún ẹnì kan kó sì kà á sí ẹ̀bùn tó dáa jù. Tẹ́ni náà bá mọyì ẹ̀bùn náà ló máa fi hàn bí ẹ̀bùn náà ti ṣe pàtàkì tó.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Ni Ẹ̀bùn Tó Dáa Ju Gbogbo Ẹ̀bùn Lọ?

Nínú ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ti fún aráyé, ọ̀kan wà níbẹ̀ tó dáa jù lọ.

Báwo Ni Jésù Ṣe Rí Gan-an?

Ọjọ́ pẹ́ táwọn èèyàn ti ń yàwòrán Jésù. Kí ni Ìwé Mímọ́ sọ nípa bí ìrísí Jésù ṣe rí?

Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Àṣìṣe

Gbogbo wa la máa ń ṣe àṣìṣe, láìka ọjọ́ orí wa àti ìrírí tá a ní sí. Àmọ́ kí la lè ṣe nígbà tá a bá ṣàṣìṣe?

Kí Nìdí Tí Oríṣiríṣi Bíbélì Fi Wà?

Kà nípa òótọ́ pàtàkì kan tó máa jẹ́ kó o mọ ìdí tí oríṣiríṣi ìtumọ̀ Bíbélì fi wà.

Ṣé Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Ṣe Ọdún Kérésìmesì?

Ṣé àwọn tó tiẹ̀ sún mọ́ Jésù dáadáa náà ṣayẹyẹ ọdún Kérésìmesì?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Amágẹ́dọ́nì jẹ́ ọ̀rọ̀ tó máa ń bani lẹ́rù, àmọ́ kí ló túmọ̀ sí?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ló Dé Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Ṣe Kérésìmesì?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ èèyàn mọ ibi tí Kérésìmesì ti ṣẹ̀ wá, síbẹ̀ wọ́n ń ṣe é. Wo ìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í fi í ṣe é.