Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀
KÍ LÈRÒ RẸ?
Ṣé Ọlọ́run fẹ́ ká máa kú? Bíbélì sọ pé: “[Ọlọ́run] yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ní ojú wọn, ikú kì yóò sì sí mọ́.”—Ìṣípayá 21:4.
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí ṣàlàyé ohun tí Bíbélì sọ nípa ìyè àti ikú.