Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ILÉ ÌṢỌ́ No. 3 2020 | Ọlọ́run Ìfẹ́ Máa Bù Kún Ẹ Títí Láé

Àwọn nǹkan rere wo ni Ọlọ́run ṣèlérí fún aráyé? Ṣé o gbà pé òótọ́ lohun tó sọ nínú Ọ̀rọ̀ rẹ̀? Àwọn àpilẹ̀kọ tó tẹ̀ lé e yìí máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn kan lára ìlérí Ọlọ́run àti ìdí tó fi yẹ kó o gbà wọ́n gbọ́. Ó sì tún sọ bó o ṣe lè jàǹfààní àwọn nǹkan rere tí Ọlọ́run ṣèlérí.

 

Ọlọ́run Ìfẹ́ Máa Fún Ẹ Ní Ọ̀pọ̀ Ohun Rere

Ṣó wù ẹ́ kí ogun, ìwà ọ̀daràn àti àìsàn dópin láyé? Èyí kì í ṣe àlá tí kò lè ṣẹ; ìlérí Ọlọ́run ni.

Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa, Ó Sì Ń Bójú Tó Wa

Ọlọ́run dà bíi bàbá kan tó nífẹ̀ẹ́ ìdílé rẹ̀ tó sì ń bójú tó wọn. Lọ́nà wo?

Ẹlẹ́dàá Wa Jẹ́ Ká Mọ Àwọn Ohun Rere Tó Fẹ́ Ṣe

Báwo ni Ọlọ́run ṣe lo àwọn wòlí ì láti kọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ sílẹ̀ fún wa?

Ṣé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ti Yí Pa Dà Ni?

Wo ohun táwọn ọ̀mọ̀wé ṣàwárí nípa Bíbélì tá a ní lóde òní.

Àwọn Wòlíì Jẹ́ Ká Mọ Ọlọ́run

Àwọn wòlíì mẹ́ta kan wà tí wọ́n jẹ́ ka mọ Ọlọ́run àti bá a ṣe lè gba ìbùkún rẹ̀.

Máa Gbàdúrà Kó O Lè Rí Ojú Rere Ọlọ́run

Báwo la ṣe lè gbàdúrà lọ́nà tí Ọlọ́run á fi gbọ́ àdúrà wa?

Àwọn Tó Ń Ṣègbọràn Sí Ọlọ́run Máa Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún

Wo ọ̀nà méjì tá a lè gbà rí ìbùkún Ọlọ́run tá a bá jẹ́ onígbọràn.

Bí A Ṣe Lè Fìfẹ́ Hàn Sí Ọmọnìkejì Wa

Kì í fìgbà gbogbo rọrùn láti máa fìfẹ́ hàn sáwọn èèyàn, àmọ́ kò kọjá ohun tá a lè ṣe.

Ẹni Tó Ń Ran Aláìní Lọ́wọ́ Máa Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún

Tá a bá ń ran aláìní lọ́wọ́, báwo nìyẹn ṣe máa jẹ́ ká rí ojú rere àti ìbùkún Ọlọ́run?

Ẹlẹ́dàá Wa Máa Bù Kún Ẹ Títí Láé

Báwo ni nǹkan ṣe máa rí láyé nígbà tí Ọlọ́run bá mú ìlérí tó ṣe fún Ábúráhámù ṣẹ?

Ṣé O Ti Béèrè Rí?

Wo ìdáhùn àwọn ìbéèrè tí ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń béèrè nípa ìṣòro ìgbésí ayé àti ìbéèrè nípa Ọlọ́run.