Yorùbá
Ṣé O Ti Béèrè Àwọn Ìbéèrè Yìí Rí?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/2025009/univ/art/2025009_univ_sqr_xl.jpg
wp25 No. 1 ojú ìwé 16

Ṣé O Ti Béèrè Àwọn Ìbéèrè Yìí Rí?

Ṣé O Ti Béèrè Àwọn Ìbéèrè Yìí Rí?
  • Tó bá jẹ́ pé gbogbo èèyàn ló ń fẹ́ àlàáfíà, kí nìdí táwọn èèyàn fi ń bára wọn jagun?

  • Ṣé ọkàn èèyàn lè balẹ̀ nínú ayé tí rògbòdìyàn kún inú ẹ̀ yìí?

  • Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tí kò ní sí ogun mọ́?

Bíbélì dáhùn àwọn ìbéèrè yìí, àwọn ìdáhùn náà lè yà ẹ́ lẹ́nu. Àmọ́ ó dájú pé ó máa tù ẹ́ nínú.

Torí náà, á dáa kó o ṣàyẹ̀wò ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìbéèrè pàtàkì yìí. A rọ̀ ẹ́ pé kó o ka Ilé Ìṣọ́ yìí kó o lè mọ̀ sí i.