ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti November 10–December 7, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 36

“Pe Àwọn Alàgbà”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 10-16, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 37

Ohun Tó Yẹ Ká Ṣe Táwọn Èèyàn Bá Rẹ́ Wa Jẹ

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 17-23, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 38

Máa Bọ̀wọ̀ Fáwọn Èèyàn

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 24-30, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 39

Tètè Ran Àwọn Tó Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́ Lọ́wọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 1-7, 2025.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Mú Ká ‘Dàgbà Níbi Tó Gbìn Wá Sí’

Mats àti Ann-Catrin Kassholm sọ̀rọ̀ nípa ọ̀pọ̀ ọdún tí wọ́n ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, ṣe ló dà bíi pé à ń gbìn wọ́n, à ń fà wọ́n tu, a sì ń tún wọn gbìn sáwọn ibi tí ètò Ọlọ́run rán wọn lọ.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ẹni tó kọ ìwé Òwe 30:18, 19 sọ pé “ọ̀nà ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀dọ́bìnrin” ‘kọjá òye òun.’ Kí ló ń sọ?

GBÓLÓHÙN KAN LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Jésù “Kọ́ Ìgbọràn”

Báwo ni Jésù ṣe kọ́ ìgbọràn bó ṣe wà ní Hébérù 5:8?