ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2023
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti November 6–December 10, 2023 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 37
Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Bíi Ti Sámúsìn
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 6-12, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 38
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Báwo Lẹ Ṣe Fẹ́ Káyé Yín Rí?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 13-19, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 39
Tó O Bá Ní Ìwà Tútù, Wàá Di Alágbára
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 20-26, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 40
Bíi Ti Pétérù, Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 27–December 3, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 41
Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Lẹ́tà Méjì Tí Pétérù Kọ
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 4-10, 2023.

