ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ November 2025
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti January 5–February 1, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ 44
Bí Àwọn Tó Ti Darúgbó Ṣe Lè Máa Láyọ̀
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 5-11, 2026.
Ṣé Ó Yẹ Kí N Ṣì Máa Wakọ̀?
Àwọn nǹkan táá jẹ́ kó o mọ̀ bóyá kó o ṣì máa wakọ̀ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan tàbí kó o má wà á mọ́.
ÀPILẸ̀KỌ 45
Ohun Tó O Lè Ṣe Kínú Ẹ Lè Máa Dùn Tó O Bá Ń Tọ́jú Èèyàn Ẹ
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 12-18, 2026.
ÀPILẸ̀KỌ 46
Jésù Ni Àlùfáà Àgbà Tó Ń Bá Wa Kẹ́dùn
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 19-25, 2026.
Ẹ Máa “Pa Ìṣọ̀kan Ẹ̀mí Mọ́”
Ẹnì kọ̀ọ̀kan wa gbọ́dọ̀ sapá kí ìṣọ̀kan lè wà nínú ìjọ. Kí la lè ṣe tẹ́nì kan nínú ìjọ bá ṣe ohun tó dùn wá?
Àpilẹ̀kọ Tó Ń Tu Àwọn Obìnrin Tí Wọ́n Hùwà Ìkà sí Nínú
Wàá rí bá a ṣe pín ìwé náà “Ọ̀rọ̀ Ààbò Àwọn Obìnrin—Ohun Tí Bíbélì Sọ” fáwọn tó wà níbi tí wọ́n ti ń bójú tó àwọn obìnrin tí wọ́n hùwà ìkà sí.
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Kí lohun tí Jèhófà máa fi sọ́kàn àwọn orílẹ̀-èdè lọ́jọ́ iwájú?
Máa Lo “Ẹ̀bùn Ẹ̀mí” Tó O Ní
Báwo la ṣe lè lo “ẹ̀bùn ẹ̀mí” tá a ní láti mú kí ìgbàgbọ́ àwọn ará túbọ̀ lágbára?

