ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ November 2023

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti January 8–February 4, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 46

Jèhófà Fi Dá Wa Lójú Pé Òun Máa Sọ Ayé Di Párádísè

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 8-14, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 47

Bá A Ṣe Lè Mú Kí Ìfẹ́ Tá A Ní Sáwọn Ará Túbọ̀ Lágbára

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 15-21, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 48

Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 22-28, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 49

Ṣé Jèhófà Máa Dáhùn Àdúrà Mi?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 29–​February 4, 2024.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Dáàbò Bò Mí Torí Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé E

Ìtàn Ìgbésí Ayé: Israel Itajobi.

Ọwọ́ Hulda Tẹ Ohun Tó Ń Wá

Báwo ni Hulda ṣe rówó ra tablet tó fi ń wàásù, tó sì fi ń ṣèpàdé?