ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ May 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti July 14–August 17, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 19

Fara Wé Àwọn Áńgẹ́lì Olóòótọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 14-20, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 20

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Pé Ó Máa Tù Ẹ́ Nínú

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 21-27, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 21

Ẹ Máa Wá Ìlú Tó Máa Wà Títí Láé

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 28–August 3, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 22

Jésù Kọ́ Wa Pé Orúkọ Jèhófà Ló Ṣe Pàtàkì Jù

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 4-10, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 23

Ṣé O Gbà Pé Orúkọ Jèhófà Ló Ṣe Pàtàkì Jù?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 11-17, 2025.

OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́

Múra Ọkàn Ẹ Sílẹ̀

Báwo la ṣe lè múra ọkàn wa sílẹ̀ tá a bá fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?