ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2026

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 2–April 5, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

MARCH 2-8, 2026

Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 2-8, 2026.

MARCH 9-15, 2026

Jèhófà Máa Jẹ́ Kó O Borí Èrò Tí Kò Tọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 9-15, 2026.

MARCH 16-22, 2026

Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Ìràpadà?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 16-22, 2026.

MARCH 23-29, 2026

Kí Lo Máa Ṣe Kó O Lè Fi Hàn Pé O Mọyì Ìràpadà?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 23-29, 2026.

MARCH 30–APRIL 5, 2026

Máa Sọ Òtítọ́ Lọ́nà Tó Ń Tuni Lára

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 30–April 5, 2026.

OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́

Máa Fojú Inú Wo Ohun Tó Ò Ń Kà Nínú Bíbélì

Wàá rí àwọn nǹkan tó o lè ṣe kó o lè máa fojú inú wo ohun tó ò ń kà nínú Bíbélì.