ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2026

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 6–May 3, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

APRIL 6-12, 2026

Bó O Ṣe Lè Ran Àwọn Mọ̀lẹ́bí Ẹ Tí Kì Í Ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lọ́wọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 6-12, 2026.

APRIL 13-19, 2026

Ohun Tí Ìrìbọmi Jẹ́ àti Ìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 13-19, 2026.

APRIL 20-26, 2026

Má Ṣe Fi Ìrìbọmi Falẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 20-26, 2026.

APRIL 27–MAY 3, 2026

Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Àwọn Ohun Tó Lè Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Tó O Bá Ṣèrìbọmi?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 27–May 3, 2026.

“Àwọn Ọmọ Jẹ́ Ogún Láti Ọ̀dọ̀ Jèhófà”

Báwo làwọn òbí ṣe lè pèsè àwọn nǹkan táwọn ọmọ wọ́n nílò, kí wọ́n máa ṣìkẹ́ wọn, kí wọ́n sì máa kọ́ wọn lohun táá jẹ́ kí wọ́n lè túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ìgbà wo làwọn orílẹ̀-èdè máa kéde “àlàáfíà àti ààbò”?

ÀWỌN TÍ BÍBÉLÌ SỌ̀RỌ̀ WỌN

Ọbadáyà Bẹ̀rù Ọlọ́run

Báwo ni àpẹẹrẹ Ọbadáyà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ ká lè ní ìbẹ̀rù Jèhófà?