ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 10–​July 7, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 14

“Ẹ Jẹ́ Ká Tẹ̀ Síwájú, Ká Dàgbà Nípa Tẹ̀mí”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 10-16, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 15

Túbọ̀ Fọkàn Tán Jèhófà àti Ètò Ẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 17-23, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 16

Bí Iṣẹ́ Ìwàásù Ṣe Lè Túbọ̀ Máa Fún Ẹ Láyọ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 24-30, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 17

Má Kúrò Nínú Párádísè Tẹ̀mí Láé

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 1-7, 2024.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Ṣàṣeyọrí, Láìka Kùdìẹ̀-Kudiẹ Mi Sí

Arákùnrin Erkki Mäkelä sọ bí Jèhófà ṣe yanjú àwọn ìṣòro òun nígbà tóun ń ṣiṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún àtìgbà tóun ń ṣiṣẹ́ míṣọ́nnárì lágbègbè Kòlóńbíà, níbi táwọn ẹgbẹ́ kan ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí ìjọba.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí nìdí táwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì fi wà lára ọmọ ogun Ọba Dáfídì?