JÍ! No. 1 2016 | Ṣé Ìsìn ti Fẹ́ Kógbá Wọlé?

Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn tó ní èrò tó yàtọ̀ síra ló ti gbé irú ìgbésẹ̀ kan náà.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé Ìsìn ti Fẹ́ Kógbá Wọlé?

Bíbélì ti sọ tẹ́lẹ̀ nípa ohun tó ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn onísìn.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Òpin Ayé

“Ayé” wo ló máa pa run? Báwo àti ìgbà wo ló máa ṣẹlẹ̀?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Ló Máa Ń Fa Wàhálà Nínú Ilé?

Ṣé àwọn wàhálà tá a ṣàlàyé nínú àpilẹ̀kọ yìí ti ṣojú ẹ rí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bí Ẹ Ṣe Lè Dín Wàhálà Kù Nínú Ilé

Ṣé ohun mẹ́fà yìí, kó má bàa máa sí ìjà láàárín yín, kí àlàáfíà sì jọba.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé

Ṣé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì lè mú kí àlàáfíà wà níbi tí kò sí tẹ́lẹ̀? Wo ohun táwọn tó ti fi ìmọ̀ràn Bíbélì sílò sọ.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ọkàn

Ṣé ọkàn kì í kú? Ṣé ọkàn yàtọ̀ sí ara èèyàn?

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí Ara Wa Ṣe Ń Mú Kí Egbò Jiná

Báwo làwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣe wo àpẹẹrẹ yìí láti fi ṣe oríṣi ike tuntun kan?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Nígbà Téèyàn Bá Kú?

Ṣé àwọn tó ti kú mọ ohun tó ń lọ láyìíká wọn?

Ohun Táwọn Ọ̀dọ́ Sọ Nípa Owó

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè fowó pa mọ́, bó ṣe yẹ kó o ná an àti bó ò ṣe ní sọ ara rẹ di ẹrú owó.