JÍ! September 2014

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìbálòpọ̀?

Tí wọ́n bá bi ẹ́ pé, ‘Ṣó o ti ní ìbálòpọ̀ rí?’ ṣé o lè fi Bíbélì ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́ nípa ìbálòpọ̀?

Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fífi Nǹkan Falẹ̀

Gbọ́ ohun táwọn ọ̀dọ́ sọ nípa ewu tó wà nínú kéèyàn máa fi nǹkan falẹ̀ àti àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa jára mọ́ ohun tó ní í ṣe.

Ọlọ́run Rán Mósè Lọ sí Ilẹ̀ Íjíbítì

Mósè àti Áárónì fi ìgboyà jíṣẹ́ fún Fáráò ọba tó jẹ́ alágbára. Ẹ wa àwọn ẹ̀kọ́ yìí jáde kẹ́ ẹ sì jọ jíròrò rẹ̀ nínú ìdílé yín.