Yorùbá
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png
g01 4/8 ojú ìwé 1-2
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

April 8, 2001

Kí Ló Fa Ìṣòro—Àwọn Ìlú Ńlá?

Ńṣe làwọn èèyàn ń rọ́ wìtìwìtì lọ sáwọn ìlú ńlá. Àmọ́, wàhálà àtibójútó àwọn èèyàn yìí ti kó ọ̀pọ̀ ìlú ńlá sínú ìyọnu.

3 “Àwọn Ìlú Ńlá Ń kún Sí I”

4 Kí Ló Fa Ìṣòro—Àwọn Ìlú ńlá?

8 Báwo Lọjọ́ Iwájú Àwọn Ìlú Ńlá Ṣe Máa Rí O?

11 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

12 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .

Báwo Ni Màá Ṣe Sọ fún Un Pé Mi Ò Ṣe?

15 Ọ̀nà Tí Wọ́n Ń Gbà Jagun Lóde Òní

17 Ohun Ìjà Kéékèèké, Ìṣòro Ńláńlá

21 Ìrètí Wo Ló Ń bẹ Pé A Óò Kápá Ohun Ìjà?

29 Wíwo Ayé

31 Sísọ Aṣálẹ̀ Di Ilẹ̀ Eléso

32 Àràádọ́ta Ọ̀kẹ́ Yóò Lọ Síbẹ̀—Ṣé Ìwọ Náà Á Lọ?

Ojú Ìwòye Bíbélì 24

Ṣé Ìsọfúnni Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Àlá Jẹ́?

Wọ́n Lè Jí Ohun Ìdánimọ̀ Rẹ Lọ 26

Ṣọ́ra fún ìwà ọ̀daràn kan tó ti gbalé gbòde báyìí—jíjí ohun ìdánimọ̀! Báwo lo ṣe lè dáàbò bo ara rẹ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀?