Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ October 17-23, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022336/univ/art/202022336_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 September ojú ìwé 11

October 17-23

1 ÀWỌN ỌBA 21-22

October 17-23
  • Orin 134 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 116

  • “Ìfẹ́ Máa Ń Ní Sùúrù àti Inú Rere”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni Alexandru ṣe tó fi hàn pé ó ní sùúrù àti inú rere bó tiẹ̀ jẹ́ pé òun ni olórí ìdílé? Kí ló mú kí Dorina yíwà pa dà nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín? Kí la rí kọ́ látinú ìrírí wọn?

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 23

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 50 àti Àdúrà