Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ September 28–October 4, 2020
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 September ojú ìwé 6

September 28–October 4

Ẹ́KÍSÓDÙ 29-30

September 28–October 4
  • Orin 32 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Wọ́n Mú Ọrẹ Wá fún Jèhófà”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 29:10​—Kí ló túmọ̀ sí tàwọn àlùfáà bá “gbé ọwọ́ wọn lé orí akọ màlúù”? (it-1 1029 ¶4)

    • Ẹk 30:​31-33​—Kí nìdí tí wọ́n fi gbọ́dọ̀ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣe òróró àfiyanni mímọ́, tó sì fi pa ẹni tí kò tọ́ lára? (it-1 114 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 29:​31-46 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, kó o sì bá ẹni náà sọ̀rọ̀ látorí fóònù tàbí kó o lo kámẹ́rà. (Tí kò bá ṣeé ṣe ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín, ṣe bíi pé ò ń wàásù fún ẹni kan tó wà nínú ilé, àmọ́ tí kò ṣí ilẹ̀kùn fún ẹ.) (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 113 ¶18 (th ẹ̀kọ́ 13)

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) km 1/11 4 ¶5-7; 6, àpótí​—Àkòrí: Àwọn Nǹkan Tẹ́ Ẹ Lè Ṣe Nígbà Ìjọsìn Ìdílé Yín. (th ẹ̀kọ́ 20)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI