Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ September 9-15, 2019
/assets/ct/a5f5be13b3/images/syn_placeholder_sqr.png

September 9-15

HÉBÉRÙ 9-10

September 9-15
  • Orin 10 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Òjìji Àwọn Nǹkan Rere Tó Ń Bọ̀”: (10 min.)

    • Heb 9:12-14—Ẹ̀jẹ̀ Kristi ṣeyebíye ju ẹ̀jẹ̀ àwọn ewúrẹ́ àti tàwọn akọ màlúù lọ (it-1 862 ¶1)

    • Heb 9:24-26—Ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo ni Kristi gbé ìtóye ẹbọ rẹ̀ lọ fún Ọlọ́run, kò sì ní tún un ṣe mọ́ láé (cf 183 ¶4)

    • Heb 10:1-4—Òfin yẹn ṣàpẹẹrẹ nǹkan ńlá tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú (it-2 602-603)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Heb 9:16, 17—Kí ni ìtumọ̀ àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí? (w92 3/1 31 ¶4-6)

    • Heb 10:5-7—Ìgbà wo ni Jésù sọ̀rọ̀ yìí, kí ló sì ní lọ́kàn? (it-1 249-250)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 9:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 89

  • Ṣé O Mọyì Àwọn Ìpàdé Wa? (Sm 27:11): (12 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò. Lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí:

    • Àwọn nǹkan wo ni Jésù tó jẹ́ Àlùfáà Àgbà wa ṣe, tó ṣe wá láǹfààní?

    • Ọ̀nà mẹ́ta wo la lè gbà fi hàn pé a mọrírì ohun tó ṣe?

  • Máa Fetí Sílẹ̀ Nípàdé: (3 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò. Lẹ́yìn náà, ní kí àwọn ọmọdé sọ ìdí tó fi yẹ kí wọ́n máa fetí sílẹ̀ nípàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 10 ¶5-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 108 àti Àdúrà