Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ September 16-22, 2019
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

September 16-22

HÉBÉRÙ 11

September 16-22
  • Orin 119 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìgbàgbọ́?”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Heb 11:4​—Kí ló jẹ́ kí Ébẹ́lì ní ìgbàgbọ́ tó lágbára? (it-1 804 ¶5)

    • Heb 11:5​—Báwo ni Jèhófà ṣe san Énọ́kù lẹ́san torí ìgbàgbọ́ tó ní? (wp17.1 12-13)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 11:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI