ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní September 2018

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní September 2018
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń wá a tọkàntọkàn?

Bíbélì: 1Pe 5:6, 7

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe nífẹ̀ẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa tó?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe nífẹ̀ẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa tó?

Bíbélì: Mt 10:29-31

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run mọ bí nǹkan ṣe ń rí lára wa?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run mọ bí nǹkan ṣe ń rí lára wa?

Bíbélì: Sm 139:1, 2, 4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àǹfààní wo ló wà nínú bí Ọlọ́run ṣe ń bójú tó wa?