Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ September 11-​17, 2017
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

September 11-​17

ÌSÍKÍẸ́LÌ 46-48

September 11-​17
  • Orin 134 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Máa Gbádùn Tí Wọ́n Bá Kúrò Nígbèkùn”: (10 min.)

    • Isk 47:1, 7-12​—Ilẹ̀ wọn máa di ilẹ̀ ọlọ́ràá (w99 3/1 10 ¶11-12)

    • Isk 47:13, 14​—Ìdílé kọ̀ọ̀kan ló máa gba ogún (w99 3/1 10 ¶10)

    • Isk 48:9, 10​—Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ sí í pín ilẹ̀ fún àwọn èèyàn, wọ́n á kọ́kọ́ ya apá ibi tó dára gan-an sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí “ọrẹ” fún Jèhófà

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Isk 47:1, 8; 48:30, 32-34​—Kí nìdí tí àwọn Júù tí wọ́n kó nígbèkùn yẹn kò fi retí pé kí gbogbo nǹkan tí Ìsíkíẹ́lì rí nínú ìràn tẹ́ńpìlì yẹn rí bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́? (w99 3/1 11 ¶14)

    • Isk 47:6​—Kí ni ìdí tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí fi pe Ìsíkíẹ́lì ní “ọmọ ènìyàn”? (it-2 1001)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 48:13-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI