Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

October 7-​13

JÉMÍÌSÌ 3–5

October 7-​13
 • Orin 50 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jem 4:5​—Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wo ni Jémíìsì ń tọ́ka sí níbí? (w08 11/15 20 ¶6)

  • Jem 4:​11,12​—Ọ̀nà wo lẹni tó bá ń “sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa arákùnrin kan” ṣe ń sọ̀rọ̀ “tí kò dáa nípa òfin”? (w97 11/15 20-21 ¶8)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jem 3:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 53

 • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 11 ¶7-11

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 125 àti Àdúrà