Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

October 28–​November 3

2 PÉTÉRÙ 1-3

October 28–​November 3
 • Orin 114 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn Dáadáa”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • 2Pe 1:19​—Ta ni “ìràwọ̀ ojúmọ́,” ìgbà wo ló yọ, báwo la sì ṣe mọ̀ pé ìràwọ̀ ojúmọ́ ti yọ? (w08 11/15 22 ¶2)

  • 2Pe 2:4​—Kí ni “Tátárọ́sì,” ìgbà wo sì ni Ọlọ́run ju àwọn áńgẹ́lì tó ṣọ̀tẹ̀ síbẹ̀? (w08 11/15 22 ¶3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Pe 1:​1-15 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI