Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ October 21-​27, 2019
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

October 21-​27

1 PÉTÉRÙ 3-5

October 21-​27
  • Orin 14 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Òpin Ohun Gbogbo Ti Sún Mọ́lé”: (10 min.)

    • 1Pe 4:7​—“Ẹ máa ronú jinlẹ̀, kí ẹ sì wà lójúfò, kí ẹ lè máa gbàdúrà” (w13 11/15 3 ¶1)

    • 1Pe 4:8​—“Ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín” (w99 4/15 22 ¶3)

    • 1Pe 4:9​—“Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn” (w18.03 14-15 ¶2-3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Pe 3:​19, 20​—Ìgbà wo ni Jésù wàásù fún “àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,” báwo ló sì ṣe ṣe é? (w13 6/15 23)

    • 1Pe 4:6​—Àwọn wo ni “òkú” tá a “kéde ìhìn rere” fún? (w08 11/15 21 ¶8)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Pe 3:​8-22 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI