ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”

Yorùbá
“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202019365/univ/art/202019365_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 PÉTÉRÙ 1-2

“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”

“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”

1:14-16

Kí Jèhófà tó lè tẹ́wọ́ gba ìjọsìn wa, a gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́. Kí ló túmọ̀ sí láti jẹ́ mímọ́ . . .

  • nípa tẹ̀mí?

  • nínú ìwà wa?

  • nípa tara?