Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?

Bíbélì: Jem 1:13

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?

Bíbélì: 1Jo 5:19

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?

Bíbélì: Ais 63:9

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ọlọ́run máa ṣe láti fòpin sí ìyà tó ń jẹ wá?