Àwọn ará ń ṣàtúnṣe sí pápá ìṣeré kan tí wọ́n fẹ́ lò fún àpéjọ agbègbè nílùú Frankfurt lórílẹ̀-èdè Jámánì

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI October 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ìdí tá a fi ń jìyà àti bó ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù

Báwo ni ọgbọ́n Ọlọ́run ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ nínú ohun gbogbo tá a bá ń ṣe lójoojúmọ́?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”

Kí nìdí tí fi yẹ ká jẹ́ mímọ́?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn Tó Jẹ́ Mímọ́

Báwo ni ọwọ́ tá a fi mú ìmọ́tótó ṣe kan àjọṣe wa pẹ̀lú Jèhófà?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Òpin Ohun Gbogbo Ti Sún Mọ́lé”

Báwo ló ṣe yẹ ká máa hùwà bí ìpọ́njú ńlá ṣe ń sún mọ́lé?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ìwà Mímọ́ àti Ọ̀wọ̀ Tó Jinlẹ̀ Máa Ń Yíni Lọ́kàn Pa Dà

Báwo làwọn tí ẹnì kejì wọn kì í ṣe Ẹlẹ́rìí ṣe lè fìwà jọ Kristi?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn Dáadáa”

Báwo lo ṣe lè fi hàn pé ò ń fi ọjọ́ Jèhófà sọ́kàn?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Báwo Lo Ṣe Mọyì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Tó?

Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?