Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

October 29–​November 4

JÒHÁNÙ 18-19

October 29–​November 4
 • Orin 54 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jésù Jẹ́rìí sí Òtítọ́”: (10 min.)

  • Jo 18:36​—Orí Ìjọba Mèsáyà ni òtítọ́ dá lé

  • Jo 18:37​—Jésù jẹ́rìí sí òtítọ́ nípa àwọn ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún aráyé (“jẹ́rìí sí,” “òtítọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 18:37, nwtsty)

  • Jo 18:38a​—Ó hàn pé Pílátù ò gbà pé nǹkan kan wà tó ń jẹ́ òtítọ́ (“Kí ni òtítọ́?” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 18:38a, nwtsty)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jo 19:30​—Kí ló túmọ̀ sí pé Jésù “jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́”? (“ó jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 19:30, nwtsty)

  • Jo 19:31​—Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé Nísàn 14, ọdún 33 Sànmánì Kristẹni ni Jésù kú? (“ọjọ́ Sábáàtì yẹn jẹ́ ọjọ́ ńlá” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Joh 19:31, nwtsty)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 18:1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkànnì jw.org han onílé.

 • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Bíbélì àti ìbéèrè fún ìgbà míì.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 14 ¶6-7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI