Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ October 15-​21, 2018
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

October 15-​21

JÒHÁNÙ 13-14

October 15-​21
  • Orin 100 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”: (10 min.)

    • Jo 13:5​—Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ (“wẹ ẹsẹ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 13:5, nwtsty)

    • Jo 13:12-14​—Jésù sọ fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé kí wọ́n máa ‘wẹ ẹsẹ̀ ara wọn lẹ́nì kìíní-kejì’ (“ó yẹ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 13:14, nwtsty)

    • Jo 13:15​—Gbogbo àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìrẹ̀lẹ̀ tí Jésù fi lélẹ̀ (w99 3/1 31 ¶1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 14:6​—Báwo ni Jésù ṣe jẹ́ “ọ̀nà àti òtítọ́ àti ìyè”? (“Èmi ni ọ̀nà àti òtítọ́ àti ìyè” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 14:6, nwtsty)

    • Jo 14:12​—Báwo ni àwọn tó nígbàgbọ́ nínú Jésù ṣe máa “ṣe àwọn iṣẹ́ tí ó tóbi ju” ti Jésù? (“àwọn iṣẹ́ tí ó tóbi ju ìwọ̀nyí” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 14:12, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 13:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI