Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ October 9-​15, 2017
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png

October 9-​15

DÁNÍẸ́LÌ 10-12

October 9-​15
  • Orin 31 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 ​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 ​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ kí o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.11 5-6 ¶7-8​—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI