Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ October 30–​November 5, 2017
/assets/ct/08c9985de2/images/syn_placeholder_sqr.png

October 30–​November 5

JÓẸ́LÌ 1-3

October 30–​November 5
  • Orin 143 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Káàdì ìkànnì JW.ORG

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Káàdì ìkànnì JW.ORG​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní káàdì yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ, kí o sì fi fídíò kan hàn án láti orí ìkànnì jw.org.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 196-197 ¶3-5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI