ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti December 1-7, 2025

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti December 1-7, 2025
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202025405/univ/art/202025405_univ_sqr_xl.jpg
mwb25 November ojú ìwé 9

December 1-7

ÀÌSÁYÀ 3-5

December 1-7

Orin 135 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Jèhófà Retí Pé Káwọn Èèyàn Òun Máa Ṣègbọràn sí Òun

(10 min.)

Jèhófà fara balẹ̀ ‘gbin ọgbà àjàrà’ rẹ̀, ó sì retí pé kó méso jáde (Ais 5:1, 2, 7; ip-1 73-74 ¶3-5; 76 ¶8-9)

Àjàrà igbó nìkan ni ọgbà àjàrà Jèhófà mú jáde (Ais 5:4; w06 6/15 18 ¶1)

Jèhófà sọ pé òun máa sọ ọgbà àjàrà náà di ahoro (Ais 5:5, 6; w06 6/15 18 ¶2)

BI ARA RẸ PÉ: ‘Báwo ni ìtàn yìí ṣe lè ràn mí lọ́wọ́ láti yẹra fún àwọn nǹkan tí inú Jèhófà ò dùn sí?’

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Ais 5:8, 9—Kí làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe tó bí Jèhófà nínú? (ip-1 80 ¶18-19)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi fídíò kan látinú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ han ẹnì kan, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 5)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Sọ fún ẹni náà nípa JW Library, kó o sì bá a wà á sórí fóònù ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)

6. Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn

(5 min.) Fún ẹni tó ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níṣìírí torí pé àwọn tó wà nínú ìdílé ẹ̀ ń ta kò ó. (lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 4)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 65

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 4 àti Àdúrà