Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ November 27–December 3, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023409/univ/art/202023409_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 November ojú ìwé 6

November 27–December 3

JÓÒBÙ 20-21

November 27–December 3
  • Orin 38 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Owó Kọ́ Ló Ń Mú Kéèyàn Jẹ́ Olódodo”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 20:2—Kí làwọn alàgbà lè ṣe láti ran àwọn tó ní ìdààmú ọkàn lọ́wọ́? (w95 1/1 9 ¶19)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 20:1-22 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI