ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì

Yorùbá
Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023407/univ/art/202023407_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 November ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì

Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì

Àwọn mọ̀lẹ́bí Jóòbù pa á tì (Job 19:13)

Àwọn ìránṣẹ́ Jóòbù àtàwọn ọmọdé ń fi ojú àbùkù wò ó (Job 19:​16, 18)

Àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù tímọ́tímọ́ kẹ̀yìn sí i (Job 19:19)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà tí wọ́n bá wà nínú ìṣòro?’—Owe 17:17; w22.01 16 ¶9; w21.09 30 ¶16; w90 9/1 22 ¶20.