MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú?
Àwòrán ìṣekúṣe wọ́pọ̀ gán-an lóde òní, ó sì rọrùn láti rí. Ọ̀pọ̀ èèyàn ni ò rí ohun tó burú nínú ẹ̀, títí kan àwọn tó sọ pé àwọn ń sin Ọlọ́run.
Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ṢÉ Ẹ̀ṢẸ̀ NI WÍWO ÀWÒRÁN ÌṢEKÚṢE JẸ́ LÓJÚ ỌLỌ́RUN? KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:
Báwo làwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ bó ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tí ẹnì kan bá ń wo àwòrán ìṣekúṣe?

