Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ December 18-24, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023418/univ/art/202023418_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 November ojú ìwé 12

December 18-24

JÓÒBÙ 28-29

December 18-24
  • Orin 39 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 29:24—Kí ni àpẹẹrẹ Jóòbù kọ́ wa? (g00 7/8 11 ¶3)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 28:​1-28 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI