Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ December 26, 2022–January 1, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022421/univ/art/202022421_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 November ojú ìwé 14

December 26, 2022–January 1, 2023

2 ÀWỌN ỌBA 20-21

December 26, 2022–January 1, 2023
  • Orin 41 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Ọb 21:13​—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà fi irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú díwọ̀n Jerúsálẹ́mù? (it-2 240 ¶1)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 21:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI