Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ December 12-18, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022415/univ/art/202022415_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 November ojú ìwé 10

December 12-18

2 ÀWỌN ỌBA 16-17

December 12-18
  • Orin 115 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Ọb 17:29—Àwọn wo ni “ará Samáríà” tó wà nínú ẹsẹ Bíbélì yìí, àwọn wo la sì pè bẹ́ẹ̀ nígbà tó yá? (it-2 847)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 17:18-28 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI