ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ November 8-14, 2021

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ November 8-14, 2021
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021404/univ/art/202021404_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 November ojú ìwé 4

November 8-14

JÓṢÚÀ 20-22

November 8-14
  • Orin 120 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Joṣ 21:43, 44​—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ilẹ̀ Kénáánì kọ́ làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun, kí ló fi hàn pé ohun tó wà nínú ẹsẹ yìí nímùúṣẹ? (it-1 402 ¶3)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 20:1–21:3 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 119

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 15 ¶18-23

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 121 àti Àdúrà