ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn

Yorùbá
Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021407/univ/art/202021407_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 November ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn

Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn

‘Ẹ máa ṣọ́ra ní gbogbo ìgbà, kí ẹ sì máa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà’ (Joṣ 23:11)

Ẹ má ṣe bá àwọn orílẹ̀-èdè náà da nǹkan pọ̀ (Joṣ 23:12, 13; it-1 75)

Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà (Joṣ 23:14; w07 11/1 26 ¶19-20)

Tá a bá ń tẹ̀ lé ìmọ̀ràn tí Jóṣúà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, báwo nìyẹn ṣe lè mú ká jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?