ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní 2020

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní 2020
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 November ojú ìwé 1

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?

Bíbélì: Mt 6:9, 10 tàbí Ais 9:6, 7

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?

○● ÌPADÀBẸ̀WÒ

Ìbéèrè: Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?

Bíbélì: Mt 14:19, 20 tàbí Sm 72:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣàkóso Ayé?