ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Mósè Tẹ̀ Lé Ìtọ́ni Tí Jèhófà Fún Un

Yorùbá
Mósè Tẹ̀ Lé Ìtọ́ni Tí Jèhófà Fún Un
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202020403/univ/art/202020403_univ_sqr_xl.jpg
mwb20 November ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 39-40

Mósè Tẹ̀ Lé Ìtọ́ni Tí Jèhófà Fún Un

Mósè Tẹ̀ Lé Ìtọ́ni Tí Jèhófà Fún Un

39:32, 43; 40:1, 2, 16

Mósè tẹ̀ lé gbogbo ìtọ́ni tí Jèhófà fún wọn lórí bí wọ́n ṣe máa kọ́ àgọ́ ìjọsìn. Ó yẹ káwa náà máa tẹ̀ lé àwọn ìtọ́ni tí ètò Jèhófà bá fún wa, ká sì máa ṣègbọràn délẹ̀délẹ̀. Kódà táwọn ìtọ́ni yẹn ò bá fi bẹ́ẹ̀ ṣe pàtàkì lójú wa tàbí tá ò bá mọ ìdí tí wọ́n fi fún wa nírú ìtọ́ni bẹ́ẹ̀.​—Lk 16:10.

Kí nìdí tó fi yẹ ká tẹ̀ lé ìtọ́ni tí wọ́n bá fún wa nípa bó ṣe yẹ . . .

  • ká wàásù?

  • ká múra sílẹ̀ fún ìtọ́jú pàjáwìrì?

  • ká múra sílẹ̀ kí àjálù tó dé?