ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé

Yorùbá
Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202019403/univ/art/202019403_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 JÒHÁNÙ 1-5

Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé

Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé

2:15-17

Sátánì máa ń lo àwọn nǹkan mẹ́ta táyé ń gbé lárugẹ yìí kó lè mú ká jìnnà sí Jèhófà. Báwo lo ṣe lè ṣàlàyé ẹ̀ fẹ́nì kan?

  • “Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara”

  • “Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú”

  • “Fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn”