Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ỌBADÁYÀ 1–JÓNÀ 4

Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ

Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ

Ìwé Jónà fi hàn pé Jèhófà kì í pa wá tì nígbà tá a bá ṣe àṣìṣe. Àmọ́, ó fẹ́ ká kẹ́kọ̀ọ́ nínú àwọn àṣìṣe wa ká sì ṣàtúnṣe tó yẹ.

Jon 1:3

Àṣìṣe wo ni Jónà ṣe nígbà tí Jèhófà rán an níṣẹ́?

Jon 2:​1-10

Kí ni Jónà gbàdúrà fún, báwo sì ni Jèhófà ṣe dáhùn àdúrà rẹ̀?

Jon 3:​1-3

Báwo ni Jónà ṣe fi hàn pé ó kẹ́kọ̀ọ́ nínú àwọn àṣìṣe rẹ̀?