ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti May 11-17, 2026

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti May 11-17, 2026
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202026162/univ/art/202026162_univ_sqr_xl.jpg
mwb26 May ojú ìwé 4

May 11-17

ÀÌSÁYÀ 60-61

May 11-17

Orin 146 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Dìde, Ìwọ Obìnrin, Tan Ìmọ́lẹ̀”

(10 min.)

Jerúsálẹ́mù àtijọ́ ni obìnrin tó wà ní Àìsáyà 60:1 ń ṣàpẹẹrẹ (Ais 60:1, 2; w24.07 30 ¶1-2)

Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tí Àìsáyà orí 60 sọ nípa bá a ṣe máa mú Jerúsálẹ́mù pa dà bọ̀ sípò ò ṣẹ tán lásìkò yẹn (w24.07 30 ¶3-4)

Báwo làwọn àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe túbọ̀ ṣẹ sára “Jerúsálẹ́mù ti òkè”? (Ga 4:26; w24.07 30 ¶5–31 ¶2)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Ais 61:1—Báwo ni Jésù ṣe mú kí àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣẹ? (Lk 4:18-21; w19.12 11 ¶10-11)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Jẹ́ kí ẹni náà mọ orúkọ Ọlọ́run. (lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 3)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Nígbà tẹ́ ẹ jọ sọ̀rọ̀ tẹ́lẹ̀, ẹni náà sọ pé èèyàn òun kan kú. (lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 4)

6. Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 156

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 119 àti Àdúrà