ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti June 24-30, 2024

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti June 24-30, 2024
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202024168/univ/art/202024168_univ_sqr_xl.jpg
mwb24 May ojú ìwé 14-15

June 24-30

SÁÀMÙ 54-56

June 24-30

Orin 48 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Ọlọ́run Ò Ní Fi Ẹ́ Sílẹ̀

(10 min.)

Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà bíi ti Dáfídì tí ẹ̀rù bá ń bà ẹ́ (Sm 56:1-4; w06 8/1 22 ¶10-11)

Jèhófà mọyì bó o ṣe ń fara dà á, ó sì máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ (Sm 56:8; cl 243 ¶9)

Jèhófà ò ní fi ẹ́ sílẹ̀. Kò sì ní jẹ́ kí ohunkóhun ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú rẹ̀ jẹ́ (Sm 56:9-13; Ro 8:36-39; w22.06 18 ¶16-17)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 55:12, 13—Ṣé Jèhófà ló kádàrá Júdásì pé kó da Jésù? (it-1 857-858)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún ẹni náà ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 11)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. (lmd ẹ̀kọ́ 7 kókó 4)

6. Àsọyé

(5 min.) w23.01 29-30 ¶12-14—Àkòrí: Ìfẹ́ Tá A Ní fún Kristi Ń Mú Ká Nígboyà. Wo àwòrán. (th ẹ̀kọ́ 9)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin “Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà” (èyí tó lọ́rọ̀ orin)

7. A Lè Láyọ̀ Bá A Tiẹ̀ Ń Dojú Kọ . . . Idà

(5 min.) Ìjíròrò.

Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:

  • Kí lo rí kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Arákùnrin Dugbe tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ẹ̀rù bá ń bà ẹ́?

8. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June

(10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà.

9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 11 ¶11-19

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 70 àti Àdúrà